Jeremáyà 30:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ẹ jọ̀wọ́, ẹ bá mi béèrè bóyá ọkùnrin lè bímọ. Kí wá nìdí tí gbogbo ọ̀dọ́kùnrin tí mo rí fi ń fọwọ́ ti ikùn* Bí obìnrin tó ń rọbí?+ Kí nìdí tí gbogbo ojú sì fi funfun?
6 Ẹ jọ̀wọ́, ẹ bá mi béèrè bóyá ọkùnrin lè bímọ. Kí wá nìdí tí gbogbo ọ̀dọ́kùnrin tí mo rí fi ń fọwọ́ ti ikùn* Bí obìnrin tó ń rọbí?+ Kí nìdí tí gbogbo ojú sì fi funfun?