Àìsáyà 9:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Torí a ti bí ọmọ kan fún wa,+A ti fún wa ní ọmọkùnrin kan;Àkóso* sì máa wà ní èjìká rẹ̀.+ Orúkọ rẹ̀ á máa jẹ́ Àgbàyanu Agbani-nímọ̀ràn,+ Ọlọ́run Alágbára,+ Baba Ayérayé, Ọmọ Aládé Àlàáfíà.
6 Torí a ti bí ọmọ kan fún wa,+A ti fún wa ní ọmọkùnrin kan;Àkóso* sì máa wà ní èjìká rẹ̀.+ Orúkọ rẹ̀ á máa jẹ́ Àgbàyanu Agbani-nímọ̀ràn,+ Ọlọ́run Alágbára,+ Baba Ayérayé, Ọmọ Aládé Àlàáfíà.