Sefanáyà 2:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ó máa na ọwọ́ rẹ̀ sí àríwá, á sì pa Ásíríà run,Á sọ Nínéfè di ahoro,+ á sì gbẹ bí aṣálẹ̀.