Hábákúkù 2:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àkókò tí ìran náà máa ṣẹ kò tíì tó,Ó ń yára sún mọ́lé,* kò sì ní lọ láìṣẹ. Tó bá tiẹ̀ falẹ̀,* ṣáà máa retí rẹ̀!*+ Torí yóò ṣẹ láìkùnà. Kò ní pẹ́ rárá!
3 Àkókò tí ìran náà máa ṣẹ kò tíì tó,Ó ń yára sún mọ́lé,* kò sì ní lọ láìṣẹ. Tó bá tiẹ̀ falẹ̀,* ṣáà máa retí rẹ̀!*+ Torí yóò ṣẹ láìkùnà. Kò ní pẹ́ rárá!