-
Diutarónómì 28:28, 29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Jèhófà máa mú kí o ya wèrè, kí o fọ́jú,+ kí nǹkan sì dà rú fún ọ.* 29 Wàá máa táràrà kiri ní ọ̀sán gangan, bí afọ́jú ṣe máa ń táràrà torí ó wà lókùnkùn,+ o ò sì ní ṣàṣeyọrí nínú gbogbo ohun tí o bá ń ṣe; wọ́n á máa lù ọ́ ní jìbìtì, wọ́n á sì máa jà ọ́ lólè léraléra, kò ní sẹ́ni tó máa gbà ọ́ sílẹ̀.+
-