Ìdárò 5:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Jèhófà, rántí ohun tó ti ṣẹlẹ̀ sí wa. Wò wá, kí o sì rí ìtìjú wa.+