Sekaráyà 4:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ó wá sọ fún mi pé: “Ohun tí Jèhófà sọ fún Serubábélì nìyí: ‘“Kì í ṣe nípasẹ̀ àwọn ọmọ ogun tàbí nípasẹ̀ agbára,+ bí kò ṣe nípasẹ̀ ẹ̀mí mi,”+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.
6 Ó wá sọ fún mi pé: “Ohun tí Jèhófà sọ fún Serubábélì nìyí: ‘“Kì í ṣe nípasẹ̀ àwọn ọmọ ogun tàbí nípasẹ̀ agbára,+ bí kò ṣe nípasẹ̀ ẹ̀mí mi,”+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.