26 Nígbà yẹn, ohùn rẹ̀ mi ayé jìgìjìgì,+ àmọ́ ní báyìí, ó ti ṣèlérí pé: “Lẹ́ẹ̀kan sí i, kì í ṣe ayé nìkan ni màá mì jìgìjìgì, màá mi ọ̀run pẹ̀lú.”+ 27 Ọ̀rọ̀ náà “lẹ́ẹ̀kan sí i” tọ́ka sí i pé a máa mú àwọn ohun tí a mì kúrò, àwọn ohun tí a ti ṣe, kí àwọn ohun tí a ò mì lè dúró.