Diutarónómì 28:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Jèhófà máa fi ikọ́ ẹ̀gbẹ kọ lù ọ́, pẹ̀lú akọ ibà,+ ara wíwú, ara gbígbóná, idà,+ ooru tó ń jó nǹkan gbẹ àti èbíbu;+ wọ́n á sì bá ọ títí o fi máa ṣègbé.
22 Jèhófà máa fi ikọ́ ẹ̀gbẹ kọ lù ọ́, pẹ̀lú akọ ibà,+ ara wíwú, ara gbígbóná, idà,+ ooru tó ń jó nǹkan gbẹ àti èbíbu;+ wọ́n á sì bá ọ títí o fi máa ṣègbé.