-
Jeremáyà 48:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Àwọn ọmọ Móábù ti wà láìsí ìyọlẹ́nu látìgbà èwe wọn,
Bíi wáìnì tó silẹ̀ sórí gẹ̀dẹ̀gẹ́dẹ̀ rẹ̀.
A kò dà á látinú ohun èlò kan sínú ohun èlò míì,
Wọn ò sì lọ sí ìgbèkùn rí.
Ìdí nìyẹn tí ìtọ́wò wọn kò fi yí pa dà,
Tí ìtasánsán wọn kò sì yàtọ̀.
-
-
Sekaráyà 1:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Wọ́n sì sọ fún áńgẹ́lì Jèhófà tó dúró láàárín àwọn igi mátílì náà pé: “A ti rìn káàkiri ayé, a sì rí i pé gbogbo ayé pa rọ́rọ́, kò sí wàhálà kankan.”+
-