Àìsáyà 35:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àwọn tí Jèhófà rà pa dà máa pa dà wá,+ wọ́n sì máa kígbe ayọ̀ wá sí Síónì.+ Ayọ̀ tí kò lópin máa dé orí wọn ládé.+ Wọ́n á máa yọ̀ gidigidi, inú wọn á sì máa dùn,Ẹ̀dùn ọkàn àti ìbànújẹ́ kò ní sí mọ́.+ Jeremáyà 31:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Wọ́n á wá, wọ́n á sì kígbe ayọ̀ ní ibi gíga Síónì+Inú wọn á dùn nítorí oore* Jèhófà,Nítorí ọkà àti wáìnì tuntun+ pẹ̀lú òróró,Nítorí àwọn ọmọ inú agbo ẹran àti ọ̀wọ́ ẹran.+ Wọ́n* á dà bí ọgbà tí a bomi rin dáadáa,+Wọn kò sì ní ráágó mọ́.”+
10 Àwọn tí Jèhófà rà pa dà máa pa dà wá,+ wọ́n sì máa kígbe ayọ̀ wá sí Síónì.+ Ayọ̀ tí kò lópin máa dé orí wọn ládé.+ Wọ́n á máa yọ̀ gidigidi, inú wọn á sì máa dùn,Ẹ̀dùn ọkàn àti ìbànújẹ́ kò ní sí mọ́.+
12 Wọ́n á wá, wọ́n á sì kígbe ayọ̀ ní ibi gíga Síónì+Inú wọn á dùn nítorí oore* Jèhófà,Nítorí ọkà àti wáìnì tuntun+ pẹ̀lú òróró,Nítorí àwọn ọmọ inú agbo ẹran àti ọ̀wọ́ ẹran.+ Wọ́n* á dà bí ọgbà tí a bomi rin dáadáa,+Wọn kò sì ní ráágó mọ́.”+