-
Míkà 5:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ọwọ́ yín máa lékè àwọn elénìní yín,
Gbogbo ọ̀tá yín sì máa pa run.”
-
-
Sekaráyà 10:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Wọn yóò dà bí àwọn jagunjagun,
Tó ń tẹ ẹrọ̀fọ̀ ojú ọ̀nà mọ́lẹ̀ lójú ogun.
-