Àìsáyà 62:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jèhófà ti fi ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀, apá rẹ̀ tó lágbára, búra pé: “Mi ò ní fi ọkà rẹ ṣe oúnjẹ fún àwọn ọ̀tá rẹ mọ́,Àwọn àjèjì ò sì ní mu wáìnì tuntun rẹ mọ́, èyí tí o ṣiṣẹ́ kára fún.+ Jóẹ́lì 3:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Wáìnì dídùn yóò máa sẹ̀ láti orí àwọn òkè ní ọjọ́ yẹn,+Wàrà yóò máa ṣàn lórí àwọn òkè kéékèèké,Gbogbo omi odò Júdà yóò sì máa ṣàn. Omi yóò sun láti ilé Jèhófà,+Yóò sì bomi rin Àfonífojì Àwọn Igi Bọn-ọ̀n-ní. Émọ́sì 9:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 ‘Wò ó! Ọjọ́ ń bọ̀,’ ni Jèhófà wí,‘Nígbà tí atúlẹ̀ máa lé olùkórè bá,Tí ẹni tó ń fẹsẹ̀ tẹ èso àjàrà á sì lé ẹni tó gbé irúgbìn bá;+Tí wáìnì dídùn á máa kán tótó láti ara àwọn òkè ńlá,+Tí á sì máa ṣàn jáde* lára gbogbo àwọn òkè kéékèèké.+
8 Jèhófà ti fi ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀, apá rẹ̀ tó lágbára, búra pé: “Mi ò ní fi ọkà rẹ ṣe oúnjẹ fún àwọn ọ̀tá rẹ mọ́,Àwọn àjèjì ò sì ní mu wáìnì tuntun rẹ mọ́, èyí tí o ṣiṣẹ́ kára fún.+
18 Wáìnì dídùn yóò máa sẹ̀ láti orí àwọn òkè ní ọjọ́ yẹn,+Wàrà yóò máa ṣàn lórí àwọn òkè kéékèèké,Gbogbo omi odò Júdà yóò sì máa ṣàn. Omi yóò sun láti ilé Jèhófà,+Yóò sì bomi rin Àfonífojì Àwọn Igi Bọn-ọ̀n-ní.
13 ‘Wò ó! Ọjọ́ ń bọ̀,’ ni Jèhófà wí,‘Nígbà tí atúlẹ̀ máa lé olùkórè bá,Tí ẹni tó ń fẹsẹ̀ tẹ èso àjàrà á sì lé ẹni tó gbé irúgbìn bá;+Tí wáìnì dídùn á máa kán tótó láti ara àwọn òkè ńlá,+Tí á sì máa ṣàn jáde* lára gbogbo àwọn òkè kéékèèké.+