Jeremáyà 30:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Wò ó, màá kó àwọn tó lọ sí oko ẹrú láti àgọ́ Jékọ́bù jọ,+Máa sì ṣojú àánú sí àwọn àgọ́ ìjọsìn rẹ̀. Wọ́n á tún ìlú náà kọ́ sórí òkìtì rẹ̀,+Ibi tó sì yẹ ni wọ́n á kọ́ ilé gogoro rẹ̀ tó láàbò sí.
18 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Wò ó, màá kó àwọn tó lọ sí oko ẹrú láti àgọ́ Jékọ́bù jọ,+Máa sì ṣojú àánú sí àwọn àgọ́ ìjọsìn rẹ̀. Wọ́n á tún ìlú náà kọ́ sórí òkìtì rẹ̀,+Ibi tó sì yẹ ni wọ́n á kọ́ ilé gogoro rẹ̀ tó láàbò sí.