-
Ẹ́kísódù 6:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì ni Líbínì àti Ṣíméì, gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn.+
-
-
1 Kíróníkà 23:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Àwọn ọmọ Ṣíméì ni Jáhátì, Sínà, Jéúṣì àti Bẹráyà. Àwọn mẹ́rin yìí ni ọmọ Ṣíméì.
-