Diutarónómì 3:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 pẹ̀lú Árábà àti Jọ́dánì àti ààlà náà, láti Kínérétì sí Òkun Árábà, Òkun Iyọ̀,* ní ìsàlẹ̀ àwọn gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ Písígà sí apá ìlà oòrùn.+
17 pẹ̀lú Árábà àti Jọ́dánì àti ààlà náà, láti Kínérétì sí Òkun Árábà, Òkun Iyọ̀,* ní ìsàlẹ̀ àwọn gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ Písígà sí apá ìlà oòrùn.+