Àìsáyà 66:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 “Láti òṣùpá tuntun dé òṣùpá tuntun àti láti sábáàtì dé sábáàtì,Gbogbo ẹran ara* máa wọlé wá tẹrí ba níwájú* mi,”+ ni Jèhófà wí.
23 “Láti òṣùpá tuntun dé òṣùpá tuntun àti láti sábáàtì dé sábáàtì,Gbogbo ẹran ara* máa wọlé wá tẹrí ba níwájú* mi,”+ ni Jèhófà wí.