-
1 Sámúẹ́lì 2:13, 14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ohun tí wọ́n ń ṣe sí ìpín tó tọ́ sí àwọn àlùfáà látọ̀dọ̀ àwọn èèyàn nìyí:+ Nígbàkigbà tí ọkùnrin èyíkéyìí bá ń rú ẹbọ, ìránṣẹ́ àlùfáà máa wá pẹ̀lú àmúga oníga mẹ́ta lọ́wọ́ rẹ̀, nígbà tí ẹran náà ṣì ń hó lórí iná, 14 á sì tì í bọ inú agbada tàbí ìkòkò oníga méjì tàbí ìkòkò irin tàbí ìkòkò oníga kan. Ohunkóhun tí àmúga náà bá mú wá sókè ni àlùfáà yóò mú. Bí wọ́n ṣe ń ṣe nìyẹn ní Ṣílò sí gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó ń wá síbẹ̀.
-