ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 25:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 “Kí o tún ṣe àwọn abọ́ ìjẹun rẹ̀, àwọn ife rẹ̀, àwọn ṣágo àti àwọn abọ́ rẹ̀ tí wọ́n á máa da ọrẹ ohun mímu látinú rẹ̀. Kí o fi ògidì wúrà ṣe wọ́n.+

  • Nọ́ńbà 4:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 “Kí wọ́n tún na aṣọ aláwọ̀ búlúù bo tábìlì búrẹ́dì àfihàn,+ kí wọ́n sì kó àwọn àwo ìjẹun sórí rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ife, àwọn abọ́ àti àwọn ṣágo ọrẹ ohun mímu;+ kí búrẹ́dì+ ọrẹ máa wà lórí rẹ̀ nígbà gbogbo.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́