-
Sekaráyà 6:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ara sì ń yá àwọn ẹṣin aláwọ̀ kàlákìnní náà láti jáde lọ kí wọ́n lè rìn káàkiri ayé.” Áńgẹ́lì náà wá sọ pé: “Ẹ lọ, ẹ rìn káàkiri ayé.” Wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í rìn káàkiri ayé.
-