Àìsáyà 11:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ẹ̀ka igi+ kan máa yọ látinú kùkùté Jésè,+Èéhù+ kan látinú gbòǹgbò rẹ̀ sì máa so èso. Sekaráyà 3:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “‘Àlùfáà Àgbà Jóṣúà, jọ̀ọ́ gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, ìwọ àti àwọn tí ẹ jọ ń ṣiṣẹ́ tí wọ́n jókòó níwájú rẹ, torí àwọn ọkùnrin yìí jẹ́ àmì; wò ó! mò ń mú ìránṣẹ́ mi+ tó ń jẹ́ Èéhù+ bọ̀!
8 “‘Àlùfáà Àgbà Jóṣúà, jọ̀ọ́ gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, ìwọ àti àwọn tí ẹ jọ ń ṣiṣẹ́ tí wọ́n jókòó níwájú rẹ, torí àwọn ọkùnrin yìí jẹ́ àmì; wò ó! mò ń mú ìránṣẹ́ mi+ tó ń jẹ́ Èéhù+ bọ̀!