Róòmù 9:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Mo nífẹ̀ẹ́ Jékọ́bù, àmọ́ mo kórìíra Ísọ̀.”+