Jeremáyà 49:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Nítorí náà, ẹ gbọ́ ìpinnu* tí Jèhófà ṣe lórí Édómù àti ohun tí ó ti rò nípa àwọn tó ń gbé ní Témánì:+ Ó dájú pé, a ó wọ́ àwọn ẹran kéékèèké inú agbo ẹran lọ. Ó máa sọ ibùgbé wọn di ahoro nítorí wọn.+ Jóẹ́lì 3:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Àmọ́ Íjíbítì yóò di ahoro,+Édómù yóò sì di aginjù tó dá páropáro,+Torí bí wọ́n ṣe hùwà ipá sí àwọn ará Júdà,+Ilẹ̀ àwọn tí wọ́n ti ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀.+
20 Nítorí náà, ẹ gbọ́ ìpinnu* tí Jèhófà ṣe lórí Édómù àti ohun tí ó ti rò nípa àwọn tó ń gbé ní Témánì:+ Ó dájú pé, a ó wọ́ àwọn ẹran kéékèèké inú agbo ẹran lọ. Ó máa sọ ibùgbé wọn di ahoro nítorí wọn.+
19 Àmọ́ Íjíbítì yóò di ahoro,+Édómù yóò sì di aginjù tó dá páropáro,+Torí bí wọ́n ṣe hùwà ipá sí àwọn ará Júdà,+Ilẹ̀ àwọn tí wọ́n ti ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀.+