-
Lúùkù 6:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Ó wá gbójú sókè wo àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í sọ pé:
“Aláyọ̀ ni ẹ̀yin tí ẹ jẹ́ aláìní, torí pé tiyín ni Ìjọba Ọlọ́run.+
-