Máàkù 9:50 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 Iyọ̀ dáa, àmọ́ tí iyọ̀ bá sọ adùn rẹ̀ nù pẹ́nrẹ́n, kí lẹ máa fi mú òun fúnra rẹ̀ dùn?+ Ẹ ní iyọ̀ nínú ara yín,+ kí ẹ sì jẹ́ kí àlàáfíà wà láàárín yín.”+
50 Iyọ̀ dáa, àmọ́ tí iyọ̀ bá sọ adùn rẹ̀ nù pẹ́nrẹ́n, kí lẹ máa fi mú òun fúnra rẹ̀ dùn?+ Ẹ ní iyọ̀ nínú ara yín,+ kí ẹ sì jẹ́ kí àlàáfíà wà láàárín yín.”+