Lúùkù 14:34, 35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 “Ó dájú pé iyọ̀ dáa. Àmọ́ tí iyọ̀ ò bá lágbára mọ́, kí la máa fi mú kó ní adùn?+ 35 Kò ṣeé lò fún iyẹ̀pẹ̀ tàbí ajílẹ̀. Ṣe ni àwọn èèyàn máa ń dà á nù. Kí ẹni tó bá ní etí láti gbọ́, fetí sílẹ̀.”+
34 “Ó dájú pé iyọ̀ dáa. Àmọ́ tí iyọ̀ ò bá lágbára mọ́, kí la máa fi mú kó ní adùn?+ 35 Kò ṣeé lò fún iyẹ̀pẹ̀ tàbí ajílẹ̀. Ṣe ni àwọn èèyàn máa ń dà á nù. Kí ẹni tó bá ní etí láti gbọ́, fetí sílẹ̀.”+