Kólósè 3:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àmọ́ ní báyìí, ẹ gbọ́dọ̀ mú gbogbo wọn kúrò lọ́dọ̀ yín: ìrunú, ìbínú, ìwà burúkú+ àti ọ̀rọ̀ èébú,+ kí ẹ sì mú ọ̀rọ̀ rírùn+ kúrò lẹ́nu yín. Jémíìsì 1:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, ẹ mọ èyí: Ó yẹ kí gbogbo èèyàn yára láti gbọ́rọ̀, kí wọ́n lọ́ra láti sọ̀rọ̀,+ kí wọ́n má sì tètè máa bínú,+
8 Àmọ́ ní báyìí, ẹ gbọ́dọ̀ mú gbogbo wọn kúrò lọ́dọ̀ yín: ìrunú, ìbínú, ìwà burúkú+ àti ọ̀rọ̀ èébú,+ kí ẹ sì mú ọ̀rọ̀ rírùn+ kúrò lẹ́nu yín.
19 Ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, ẹ mọ èyí: Ó yẹ kí gbogbo èèyàn yára láti gbọ́rọ̀, kí wọ́n lọ́ra láti sọ̀rọ̀,+ kí wọ́n má sì tètè máa bínú,+