1 Jòhánù 4:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Tí ẹnikẹ́ni bá sọ pé: “Mo nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run,” síbẹ̀ tó ń kórìíra arákùnrin rẹ̀, òpùrọ́ ni.+ Torí ẹni tí kò nífẹ̀ẹ́ arákùnrin rẹ̀ tó rí,+ kò lè nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run tí kò rí.+
20 Tí ẹnikẹ́ni bá sọ pé: “Mo nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run,” síbẹ̀ tó ń kórìíra arákùnrin rẹ̀, òpùrọ́ ni.+ Torí ẹni tí kò nífẹ̀ẹ́ arákùnrin rẹ̀ tó rí,+ kò lè nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run tí kò rí.+