Jémíìsì 5:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ju gbogbo rẹ̀ lọ ẹ̀yin ará mi, ẹ má ṣe búra mọ́, ì báà jẹ́ ọ̀run tàbí ayé lẹ fi búra tàbí ìbúra èyíkéyìí míì. Àmọ́ kí “Bẹ́ẹ̀ ni” yín jẹ́ bẹ́ẹ̀ ni, kí “Bẹ́ẹ̀ kọ́” yín sì jẹ́ bẹ́ẹ̀ kọ́,+ kí a má bàa dá yín lẹ́jọ́.
12 Ju gbogbo rẹ̀ lọ ẹ̀yin ará mi, ẹ má ṣe búra mọ́, ì báà jẹ́ ọ̀run tàbí ayé lẹ fi búra tàbí ìbúra èyíkéyìí míì. Àmọ́ kí “Bẹ́ẹ̀ ni” yín jẹ́ bẹ́ẹ̀ ni, kí “Bẹ́ẹ̀ kọ́” yín sì jẹ́ bẹ́ẹ̀ kọ́,+ kí a má bàa dá yín lẹ́jọ́.