-
Lúùkù 6:32, 33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 “Tí ẹ bá nífẹ̀ẹ́ àwọn tó nífẹ̀ẹ́ yín, àǹfààní kí ló jẹ́ fún yín? Torí àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ pàápàá máa ń nífẹ̀ẹ́ àwọn tó nífẹ̀ẹ́ wọn.+ 33 Tí ẹ bá sì ń ṣe rere sí àwọn tó ń ṣe rere sí yín, àǹfààní kí ló jẹ́ fún yín? Àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ pàápàá máa ń ṣe bẹ́ẹ̀.
-