-
Lúùkù 11:2-4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Torí náà, ó sọ fún wọn pé: “Nígbàkigbà tí ẹ bá ń gbàdúrà, ẹ sọ pé: ‘Baba, kí orúkọ rẹ di mímọ́.*+ Kí ìjọba rẹ dé.+ 3 Fún wa ní oúnjẹ òòjọ́ wa bí a ṣe nílò rẹ̀ lọ́jọ́ kọ̀ọ̀kan.+ 4 Kí o sì dárí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa jì wá,+ torí àwa náà máa ń dárí ji gbogbo ẹni tó jẹ wá ní gbèsè;+ má sì mú wa wá sínú ìdẹwò.’”+
-