Jòhánù 17:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Mi ò ní kí o mú wọn kúrò ní ayé, àmọ́ kí o máa ṣọ́ wọn torí ẹni burúkú náà.+ 1 Jòhánù 5:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 A mọ̀ pé ọ̀dọ̀ Ọlọ́run la ti wá, àmọ́ gbogbo ayé wà lábẹ́ agbára ẹni burúkú náà.+