Òwe 4:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ọ̀ọ́kán tààrà ni kí ojú rẹ máa wò,Bẹ́ẹ̀ ni, iwájú rẹ gan-an ni kí o tẹjú* mọ́.+ Lúùkù 11:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Ojú rẹ ni fìtílà ara. Tí ojú rẹ bá mú ọ̀nà kan,* gbogbo ara rẹ náà máa mọ́lẹ̀ yòò;* àmọ́ tó bá ń ṣe ìlara,* ara rẹ náà máa ṣókùnkùn.+ Éfésù 1:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ó ti la ojú inú* yín, kí ẹ lè mọ ìrètí tí ó pè yín láti ní, kí ẹ lè mọ ọrọ̀ ológo tó fẹ́ fi ṣe ogún fún àwọn ẹni mímọ́+
34 Ojú rẹ ni fìtílà ara. Tí ojú rẹ bá mú ọ̀nà kan,* gbogbo ara rẹ náà máa mọ́lẹ̀ yòò;* àmọ́ tó bá ń ṣe ìlara,* ara rẹ náà máa ṣókùnkùn.+
18 Ó ti la ojú inú* yín, kí ẹ lè mọ ìrètí tí ó pè yín láti ní, kí ẹ lè mọ ọrọ̀ ológo tó fẹ́ fi ṣe ogún fún àwọn ẹni mímọ́+