1 Tímótì 6:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Torí náà, tí a bá ti ní oúnjẹ* àti aṣọ,* àwọn nǹkan yìí máa tẹ́ wa lọ́rùn.+ Hébérù 13:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ẹ yẹra fún ìfẹ́ owó nínú ìgbésí ayé yín,+ bí ẹ ṣe ń jẹ́ kí àwọn nǹkan tó wà báyìí tẹ́ yín lọ́rùn.+ Torí ó ti sọ pé: “Mi ò ní fi ọ́ sílẹ̀ láé, mi ò sì ní pa ọ́ tì láé.”+
5 Ẹ yẹra fún ìfẹ́ owó nínú ìgbésí ayé yín,+ bí ẹ ṣe ń jẹ́ kí àwọn nǹkan tó wà báyìí tẹ́ yín lọ́rùn.+ Torí ó ti sọ pé: “Mi ò ní fi ọ́ sílẹ̀ láé, mi ò sì ní pa ọ́ tì láé.”+