Ìṣe 14:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nígbà tí wọ́n débẹ̀, wọ́n fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn* lókun,+ wọ́n fún wọn ní ìṣírí láti má ṣe kúrò nínú ìgbàgbọ́, wọ́n sì sọ pé: “A gbọ́dọ̀ ti inú ọ̀pọ̀ ìpọ́njú wọ Ìjọba Ọlọ́run.”+ 1 Pétérù 4:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 “Tí kò bá ní rọrùn láti gba olódodo là, kí ló máa wá ṣẹlẹ̀ sí aláìṣèfẹ́ Ọlọ́run àti ẹlẹ́ṣẹ̀?”+
22 Nígbà tí wọ́n débẹ̀, wọ́n fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn* lókun,+ wọ́n fún wọn ní ìṣírí láti má ṣe kúrò nínú ìgbàgbọ́, wọ́n sì sọ pé: “A gbọ́dọ̀ ti inú ọ̀pọ̀ ìpọ́njú wọ Ìjọba Ọlọ́run.”+