ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 9:30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Ojú wọn sì ríran. Lẹ́yìn náà, Jésù kìlọ̀ fún wọn gidigidi pé: “Kí ẹ rí i pé ẹnì kankan kò mọ ohun tó ṣẹlẹ̀ yìí.”+

  • Mátíù 12:15, 16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Nígbà tí Jésù mọ èyí, ó kúrò níbẹ̀. Ọ̀pọ̀ èèyàn tún tẹ̀ lé e,+ ó sì wo gbogbo wọn sàn, 16 àmọ́ ó kìlọ̀ fún wọn gidigidi pé kí wọ́n má ṣe jẹ́ kí àwọn èèyàn mọ òun,+

  • Máàkù 7:35, 36
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 35 Ni etí ọkùnrin náà bá là,+ kò níṣòro ọ̀rọ̀ sísọ mọ́, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í sọ̀rọ̀ dáadáa. 36 Àmọ́, ó kìlọ̀ fún wọn pé kí wọ́n má sọ fún ẹnì kankan,+ síbẹ̀ bó ṣe ń kìlọ̀ fún wọn tó ni wọ́n túbọ̀ ń kéde rẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́