Lúùkù 13:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Bákan náà, àwọn èèyàn máa wá láti ìlà oòrùn àti ìwọ̀ oòrùn, láti àríwá àti gúúsù, wọ́n sì máa jókòó* sídìí tábìlì nínú Ìjọba Ọlọ́run.
29 Bákan náà, àwọn èèyàn máa wá láti ìlà oòrùn àti ìwọ̀ oòrùn, láti àríwá àti gúúsù, wọ́n sì máa jókòó* sídìí tábìlì nínú Ìjọba Ọlọ́run.