-
Lúùkù 9:57Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
57 Bí wọ́n ṣe ń lọ lójú ọ̀nà, ẹnì kan sọ fún un pé: “Màá tẹ̀ lé ọ lọ ibikíbi tí o bá lọ.”