Máàkù 4:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Torí náà, lẹ́yìn tí wọ́n ní kí àwọn èrò náà máa lọ, wọ́n fi ọkọ̀ ojú omi náà gbé e, bó ṣe wà níbẹ̀, àwọn ọkọ̀ ojú omi míì sì wà pẹ̀lú rẹ̀.+
36 Torí náà, lẹ́yìn tí wọ́n ní kí àwọn èrò náà máa lọ, wọ́n fi ọkọ̀ ojú omi náà gbé e, bó ṣe wà níbẹ̀, àwọn ọkọ̀ ojú omi míì sì wà pẹ̀lú rẹ̀.+