Máàkù 1:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 “Kí ló pa wá pọ̀, Jésù ará Násárẹ́tì?+ Ṣé o wá pa wá run ni? Mo mọ ẹni tí o jẹ́ gan-an, Ẹni Mímọ́ Ọlọ́run ni ọ́!”+ Jémíìsì 2:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 O gbà pé Ọlọ́run kan ló wà, àbí? O ṣe dáadáa gan-an ni. Àwọn ẹ̀mí èṣù pàápàá gbà, jìnnìjìnnì sì bò wọ́n.+
24 “Kí ló pa wá pọ̀, Jésù ará Násárẹ́tì?+ Ṣé o wá pa wá run ni? Mo mọ ẹni tí o jẹ́ gan-an, Ẹni Mímọ́ Ọlọ́run ni ọ́!”+
19 O gbà pé Ọlọ́run kan ló wà, àbí? O ṣe dáadáa gan-an ni. Àwọn ẹ̀mí èṣù pàápàá gbà, jìnnìjìnnì sì bò wọ́n.+