Lúùkù 5:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Jésù fún wọn lésì pé: “Àwọn tí ara wọn le kò nílò oníṣègùn, àmọ́ àwọn tó ń ṣàìsàn nílò rẹ̀.+