-
Lúùkù 17:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Ó wá sọ fún un pé: “Dìde, kí o sì máa lọ; ìgbàgbọ́ rẹ ti mú ọ lára dá.”+
-
-
Lúùkù 18:42Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
42 Jésù wá sọ fún un pé: “Kí ojú rẹ pa dà ríran; ìgbàgbọ́ rẹ ti mú ọ lára dá.”+
-