-
Mátíù 15:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Ẹnu ya àwọn èrò náà bí wọ́n ṣe rí i tí àwọn tí kò lè sọ̀rọ̀ ń sọ̀rọ̀, tí ara àwọn aláàbọ̀ ara ń yá, tí àwọn arọ ń rìn, tí àwọn afọ́jú sì ń ríran, wọ́n sì yin Ọlọ́run Ísírẹ́lì lógo.+
-