-
Máàkù 2:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Ló bá dìde, ó gbé ibùsùn rẹ̀ lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, ó sì rìn jáde níwájú gbogbo wọn. Ẹnu ya gbogbo wọn, wọ́n sì yin Ọlọ́run lógo, wọ́n sọ pé: “A ò rí irú èyí rí.”+
-