-
Róòmù 10:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Àmọ́, báwo ni wọ́n á ṣe ké pè é tí wọn ò bá ní ìgbàgbọ́ nínú rẹ̀? Báwo sì ni wọ́n á ṣe ní ìgbàgbọ́ nínú ẹni tí wọn ò gbọ́ nípa rẹ̀? Báwo ni wọ́n á ṣe gbọ́ tí kò bá sí ẹni tó máa wàásù?
-