Jòhánù 11:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Torí náà, Tọ́másì, tí wọ́n ń pè ní Ìbejì, sọ fún àwọn tí wọ́n jọ jẹ́ ọmọ ẹ̀yìn pé: “Ẹ jẹ́ kí àwa náà lọ, ká lè bá a kú.”+ Jòhánù 20:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Lẹ́yìn náà, ó sọ fún Tọ́másì pé: “Fi ìka rẹ síbí, kí o sì wo ọwọ́ mi, ki ọwọ́ rẹ bọ ẹ̀gbẹ́ mi, kí o má sì ṣiyèméjì* mọ́, àmọ́ kí o gbà gbọ́.”
16 Torí náà, Tọ́másì, tí wọ́n ń pè ní Ìbejì, sọ fún àwọn tí wọ́n jọ jẹ́ ọmọ ẹ̀yìn pé: “Ẹ jẹ́ kí àwa náà lọ, ká lè bá a kú.”+
27 Lẹ́yìn náà, ó sọ fún Tọ́másì pé: “Fi ìka rẹ síbí, kí o sì wo ọwọ́ mi, ki ọwọ́ rẹ bọ ẹ̀gbẹ́ mi, kí o má sì ṣiyèméjì* mọ́, àmọ́ kí o gbà gbọ́.”