Máàkù 6:8, 9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ó tún pàṣẹ fún wọn pé kí wọ́n má ṣe gbé ohunkóhun dání fún ìrìn àjò náà, àfi ọ̀pá, kí wọ́n má ṣe gbé oúnjẹ àti àpò oúnjẹ, kí wọ́n má sì kó owó* sínú àmùrè owó wọn,+ 9 àmọ́ kí wọ́n wọ bàtà, kí wọ́n má sì wọ aṣọ méjì.*
8 Ó tún pàṣẹ fún wọn pé kí wọ́n má ṣe gbé ohunkóhun dání fún ìrìn àjò náà, àfi ọ̀pá, kí wọ́n má ṣe gbé oúnjẹ àti àpò oúnjẹ, kí wọ́n má sì kó owó* sínú àmùrè owó wọn,+ 9 àmọ́ kí wọ́n wọ bàtà, kí wọ́n má sì wọ aṣọ méjì.*