Róòmù 10:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Nítorí tí o bá ń fi ẹnu rẹ kéde ní gbangba pé Jésù ni Olúwa,+ tí o sì ní ìgbàgbọ́ nínú ọkàn rẹ pé Ọlọ́run gbé e dìde kúrò nínú ikú, a ó gbà ọ́ là.
9 Nítorí tí o bá ń fi ẹnu rẹ kéde ní gbangba pé Jésù ni Olúwa,+ tí o sì ní ìgbàgbọ́ nínú ọkàn rẹ pé Ọlọ́run gbé e dìde kúrò nínú ikú, a ó gbà ọ́ là.