ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Máàkù 8:38
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 38 Torí ẹnikẹ́ni tó bá tijú èmi àti àwọn ọ̀rọ̀ mi nínú ìran alágbèrè* àti ẹlẹ́ṣẹ̀ yìí, Ọmọ èèyàn náà máa tijú rẹ̀+ nígbà tó bá dé nínú ògo Baba rẹ̀ pẹ̀lú àwọn áńgẹ́lì mímọ́.”+

  • Lúùkù 9:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Torí ẹnikẹ́ni tó bá tijú èmi àti àwọn ọ̀rọ̀ mi, Ọmọ èèyàn máa tijú ẹni yẹn nígbà tó bá dé nínú ògo rẹ̀ àti ti Baba àti ti àwọn áńgẹ́lì mímọ́.+

  • 2 Tímótì 2:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 tí a bá ń fara dà á nìṣó, a tún jọ máa jọba;+ tí a bá sẹ́ ẹ, òun náà máa sẹ́ wa;+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́