Mátíù 3:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ní tèmi, mò ń fi omi batisí yín torí pé ẹ ronú pìwà dà,+ àmọ́ ẹni tó ń bọ̀ lẹ́yìn mi lágbára jù mí lọ, ẹni tí mi ò tó bọ́ bàtà rẹ̀.+ Ẹni yẹn máa fi ẹ̀mí mímọ́+ àti iná+ batisí yín. Jòhánù 1:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 (Jòhánù jẹ́rìí nípa rẹ̀, àní, ó ké jáde pé: “Ẹni yìí ni mo sọ nípa rẹ̀ pé, ‘Ẹni tó ń bọ̀ lẹ́yìn mi ti lọ níwájú mi, torí ó ti wà ṣáájú mi.’”)+
11 Ní tèmi, mò ń fi omi batisí yín torí pé ẹ ronú pìwà dà,+ àmọ́ ẹni tó ń bọ̀ lẹ́yìn mi lágbára jù mí lọ, ẹni tí mi ò tó bọ́ bàtà rẹ̀.+ Ẹni yẹn máa fi ẹ̀mí mímọ́+ àti iná+ batisí yín.
15 (Jòhánù jẹ́rìí nípa rẹ̀, àní, ó ké jáde pé: “Ẹni yìí ni mo sọ nípa rẹ̀ pé, ‘Ẹni tó ń bọ̀ lẹ́yìn mi ti lọ níwájú mi, torí ó ti wà ṣáájú mi.’”)+